Posts

ALAAFIN OF OYO IS 48YRS ON THE THRONE

Image
Hurray, Kabiyesi, His Imperial Majesty, Oba (Dr) Lamidi Olayiwola Adeyemi III, Iku Baba Yeye, Alaafin of Oyo will be 48yrs on the most ancient throne in Yorubaland on the 14th of January, 2019. Atanda, Moroundiya, Omo Ibironke Eru Atanda nyomi ba, To ba njenu wuye, Ogun ni lo, Piti Ola, Owo Baba Skimeh. Alowolodu bi Iyere, Ekun Oko Ayaba. Yankete Yankete, Yankete Yankete, Ohun meta L'Atanda se to nbi won ninu, O gbe Ade f'Oba O gba Idobale Oba .... Layiwola Akobi Adeniran To to to Iwo lari bawi Iwo to gbaya won to gba'ya won Iwo la ri ba wi. To to to. Layiwola Akobi Adeniran Gba n bata ko subu Eni to foju feni tio fokan feni Gba n bata ko subu To to to Layiwola Akobi Adeniran. Happy 48 years on the throne of the highly revered Institution of Alaafin to you Baami Alatanda Ipekun Oba of Yoruba Kingdom.

BEAUTY OF AFRICAN FASHION FROM LIZZY ANJORIN

Image

*IFURA LOOGUN ÀGBÀ* (YORUBA POETRY)

*IFURA LOOGUN ÀGBÀ* Jòjòló Akéwì jí sáyé, mo fi ògo fún Ọlọ́run Ọba Odomode Akéwì jí sáyé, mo yin Eledumare Ẹ kú Ojúmọ́ ẹyin ènìyàn mi Gẹ́gẹ́ bí ìṣe mi, mo ti wà lórí idobale Bí mo bá ti jí, dandan ni ki n ki eégún ilé Bí mo bá ti jí, dandan ni ki n ki òrìṣà ọjà Mo júbà gbogbo eyin ajunilo Jòjòló Akéwì fẹ́ pàṣamọ̀ ọ̀rọ̀ Páńṣá kò fura, Páńṣá já sina Àjà kò fura, Àjà jin Bonile kò fura, olè ni yóò jí i gbé lọ IFURA LOOGUN ÀGBÀ Taa ló kọ́ ẹ logbon tí kò fi agọ̀ kún un Ó yẹ kó o fura, kí o wo sakun ọ̀rọ̀ Jòjòló Akéwì kii pàátó ẹnu lásán Ó ní òhun tí mo rí tó fẹ́ jẹ́ kí n ṣe ẹ loore ẹnu Ọrẹ mi, farabale koo gbọ́ àlàyé ọ̀rọ̀ Bí ayé bá ń pọn ọ lé, nise lo yẹ koo máa fura Bí ayé bá ń tẹle ọ lẹyin, ó yẹ koo máa ronú wo Ọmọ aráyé burú, mo júbà ọmọ adarihunrin Àwọn ènìyàn ní ń bẹ nídìí eto ìkà Jiji tí mo jí, orin Ifá ló wá sí mi lẹ́nu Mo yẹ ifá wò, Orunmila sì bá mi sọ̀rọ̀ Ifá sọ̀rọ̀ ilẹ̀ kún Ojú odù *Òdí Méjì*  ni ifá fi sọ̀rọ̀ Ẹ jẹ́ kí n k...